jeudi 18 décembre 2014
IKEDE ! IKEDE! IKEDE! FUN GBOGBO OMO ILE AREMO NI COTE D'IVOIRE
IKEDE ! IKEDE! IKEDE! FUN GBOGBO OMO ILE AREMO NI COTE D'IVOIRE
IKEDE PATAKI FUN GBOGBO AWA OMO ILE AREMO NI ORILE EDE COTE D'IVOIRE, PAPA JULO AWA TI AWA NI IGBORO ILU ABIDJAN.
IPADE WA NI GBOGBO OJO OSE TI ANPE NI OJO ISINMI (DIMANCHE,SUNDAY) EDAKUN EJE KI ESE GBOGBO WA OMA PEJU NI IPADE KI AMA SE JE KOJE WIPE IGBA TI ABA NILO AWON EBI NIKAN LA O SESE MA YOJU SI EBI.
AWON BABA WA NI KARIN KAPO ,YIYE NI YENI ATI WIPE GBOGBO WA LA MO WIPE AGBAJO OWO LAA NFI S'OYA. EDAKUN EJE KI AMA WA SI IPADE LOORE KORE TI OJO IPADE BA TI WA. KI AMA GBAGBE WIPE ODO T'OBA GBAGBE ORISUN RE YOO GBE NI O, OKUN KAN OSI LEE GUN TITI KI OMA NI IBI TI ATI FAAWA.
OPOLOPO ANFAANI WA NIPA KI AMA WASI IPADE OLOMOLE YI DEEDE,YATO FUN PE YOO TUN FUN WA NI AYE KI ALE MO ARA WA KAAKIRI IBI TI ABA WA.
IDAGBA S'OKE ILE AREMO AJOSE GBOGBO WA NI O, IDILE NAA KONI BAJE O, ASE NI T'EDUMARE.
NIBO NI ANTI SE IPADE ?
Aaye ipade wa, wa ni marcory lehin Mosalasi awon Oyinbo Libanais Cité BIAO ,ti eba de adugbo naa ele pe si ori number yi 07 99 98 78 tabi 07 84 32 98 tabi 09 14 09 54 ki ale wa muyin lati fi yin m'ona ,anreti yin o, Alajoobi agbe wa o Amin!
Inscription à :
Publier les commentaires (Atom)
Aucun commentaire:
Enregistrer un commentaire