dimanche 4 janvier 2015

EYI NI LATI SOFUN GBOGBO AWON OMO IDILE AREMO JAKEJADO ORILE EDE COTE D'IVOIRE

EYI NI LATI SOFUN GBOGBO AWON OMO IDILE AREMO JAKEJADO ORILE EDE COTE D'IVOIRE PE IPADE ALABE SEKELE KAN YOO WAYE NI OJO JIMOH TI ISE 09 JANVIER 2015 LEHIN TI ABA KIRUN JIMOH TAN.
NI AGOGO MEJI OSAN,PIPEJU PESE GBOGBO WA SE PATAKI NITORI PE ORO IDILE YI AJOSE GBOGBO WA NI ,AWON TO SEWA SILE KONI FI WA SILE O.

IPADE WA YOO DA LORI ORO NIPA IPADE AKINLABI TI AMA GBA ALEJO RE NI OJO DIMANCHE TI ISE 11 JANVIER 2015, BAKANNA ORO LORI ADURA OLODOODUN TI AOSE NI OJO KANNA YOO WAYE NIPA IMURA SILE RE.

OMO IYA OSI NIBE OWA NBERE BAWO NI WON SE PIN KO YE O ,LOPIN IGBA TI OKO BA TIWA SI IPADE. KI EMA SE JEKI ORO WA ORI BEE RARA EJE KA PEJU KI ASI JOSE O (OGIYAN AGBE WA O .



Aucun commentaire:

Enregistrer un commentaire