vendredi 28 novembre 2014

TI OBA JE OMO ILE AREMO,EJIGBO ELEYI JE ANFAANI FUN O







Moki yi ni kiki alafia eyin omo ilu Ejigbo ni ipinle Osun papaa julo eyin omo idile aremo oba nile ,loko, lodo, Ibikibi ti olukaluku wa bawa olorun yoo je ki ako ere oko dele o.
    Ibuddo ayelujarawon yi nibi ti ati le maa pade lati ba ara wa soro lati okere (fun apere Facebook ati Google+ ati bebee lo).

Wa fun wa nibi kibi ti aba wa ,ejeki ama lo anfaani ibudo yi ,ki oje anfaani lati le ma ba ara wa soro ati lati mo ohun ti nlo nipa idile aremo oba yala awa l'ajo bi Abidjan,Togo tabi ni oke okun nibi ti ati nwa jije mimu.
 Ki Olorun oba ninu anu re ma je ki agbe s'ajo ki osi je ki ako ere oko dele . Amin!

Eje ojulowo omo ile aremo oba tabi obi to se oloko yin waye l'obinrin je omo ile areemo gbogbo wa ni ibudo yi wulo fun,gbogbo wa lape nitori ilosiwaju ile aremo ati idagbasoke ilu Ejigbo ajose gbogbo wa ni oooo....
ILU EJIGBO ONI BAJE,OBAJE TI.

Aucun commentaire:

Enregistrer un commentaire