dimanche 9 août 2015

IDUPE ! IDUPE ! IDUPE !!!!!!!!


                                                     IDUPE ! IDUPE ! IDUPE !!!!!!!!


Idile AremoOba ni orile ede cote d'ivoire n'fi asiko yii dupe loo tebi tara ati ojulumo ti won ba wa se ayeye idile ayesi Egbe Ejigbo parapo ni orile ede cote d'ivoire.

 Adupe pupo fun inawo nara  yin ati fun aponle ati ayesi ti ese fun idile wa lasiko ti won pe wa fun ayeye idile ayesi yi eyi ti o waye ni ojo satide ti o koja lo, ojo kinni osu kejo odun 2015 yi.

A dupe lowo gbogbo olomo ile Aremo fun idide yin ati inawo nara yin , bakanna ni idupe wa losi odo awon omo baba wa ninu idile Akinlabi Saaliu bi Idile Alabi , Idile Lagboye ati Idile Eja lonibu fun gbogbo akitiyan yin.

Bakanna atun dupe lowo awon Ana wa ati eyin Oree ti ewa ba wa se ayeesi yi.

Adura wa ni pe ki olorun oba o je ki ale ko oju owo ati ere oko dele o, Amin !


NI ISALE YI NI AWON AWORAN DIE NIPA AYEYE OJO NAA.............





































































                                                                           ESE PUPO



Olukede fun gbogbo ebi : Bello Abdoul Rasaq Adeniyi

Aucun commentaire:

Enregistrer un commentaire