mardi 21 juillet 2015

EJIGBO DAY TI : Oṣù Ògún AUGUST/ AOUT 2015 TI KAN IDILE AREMO EKA TI ORILE EDE COTE D'IVOIRE


EJIGBO DAY TI : Oṣù Ògún AUGUST/ AOUT 2015 TI KAN IDILE AREMO EKA TI ORILE EDE COTE D'IVOIRE.

Eyi ni lati sofun Awa Omo Idile AREMO Jakejado Orile Ede COTE D'IVOIRE pe Ajodun eye fun awa omo ilu Ejigbo, nibi ti idile si idile ti ma nse idije ariya olookan ojokan ti a mo si EJIGBO DAY ti kan idile Aremo bayi.
Ajodun yi yoo waye ni ojo kinni osu Ogun (Aout / August) odun ti a wa ninu re yi.




Latari ajodun yi ,ipade pataki yoo waye ni ile baba wa Murtada Oseni ni Marcory ni ojo Sunday / Dimanche 26 Juillet / July 2015.
NI DEDE AGOGO MEJILA OSAN (MIDI),PIPEJU PESE GBOGBO WA SE PATAKI NITORI PE ORO IDILE YI AJOSE GBOGBO WA NI ,AWON TO SEWA SILE KONI FI WA SILE O.

IPADE WA YOO DA LORI ORO NIPA EJIGBO DAY TI 1ER AOUT / 1ST AUGUST 2015.
 
 ESE PUPO ,ILU EJIGBO KONI BAJE O.

 Olukede fun gbogbo ebi : Prince Bello Abdoul Rasaq Adeniyi

Aucun commentaire:

Enregistrer un commentaire