E TATI WERE
Awon Yoruba bo won ni tati were ni t'ekute ile, Abiyamo kan ki gbo igbe omo re ki oma tati were, Eyi ni lati so fun gbogbo awa omo ile aremo ti oruko wa wa ni isale oju iwe yi ,wipe ki a tati were nitori wipe idile to se wa sile npe wa ,Osi ti di dandan ki agbo ipe awon to se wa sile.
Ni oruko gbogbo idile aremo ni an fi pe yin towo towo lati wa je ipe idile yin ni ojo Sunday 8 February 2015 (Dimanche 8 Fevrier 2015) ni ibi aye ipade wa ti o wa ni cité BIAO ni abawole Marcory ti owa ni eyin Mosalasi awon oyinbo Lebanni.
EDAKUN EYIN BABA, MAMA ATI EGBON TI ORUKO YIN WA NI ISALE IWE YI ,WIWA WA SE PATAKI PUPO FUN ANFAANI ILOSIWAJU IDILE WA.
BABA WA : MURTADA BELLO dit PEPITO (MARCORY)
BABA WA : SIKIRU BELLO (ABOBO)
BABA WA : KHALIATU BELLO (YOPOUGON)
BABA WA : MIFTAU BELLO (ABOBO)
BABA WA : MIFTAU OLANIYAN (YOPOUGON)
BABA WA : LIADI BELLO (ADJAME)
BABA WA : TAOFEEQ OLANIYAN (PORTBOUET)
BABA WA : JAMOLI MAROUF LAWANI (REMBLAIS)
BABA WA : KASEEM OLANIYAN NKANLOLA (PAILLET)
BABA WA : HABIB OLANIYAN PARIOLA ( YOPOUGON)
BABA WA : RAZAQ BELLO (ABOBO)
BABA WA : LAWAL OLANIYAN (KOUMASSI)
BABA WA : RASAQ AKINTAYO BELLO ( TREICHVILLE)
MAMA WA : MODINAT ILUPEJU (TREICHVILLE)
MAMA WA : SILIFAT OLANIYAN (TREICHVILLE)
MAMA WA : NOURAT BELLO (ADJAME)
MAMA WA : SIMBIAT BELLO (FAYA)
MAMA WA : MODINAT OLASUNKADE (KOUMASSI)
MAMA WA : SHAKIRAT MEGIDA (ADJAME)
AKIYESI PATAKI : Ejowo enikeni ti oba gbo ipe yi ki ose alaye fun enikeji re ti oba sunmon ki gbogbo wa le gbo.
Aucun commentaire:
Enregistrer un commentaire